1 Kíróníkà 26:6 BMY

6 Ọmọ Rẹ̀ Ṣémáíà ní àwọn ọmọkùnrin pẹ̀lú tí wọ́n jẹ́ olórí ní ìdílé bàbá a wọn nítorí wọ́n jẹ́ ọkùnrin tó lágbára.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:6 ni o tọ