1 Kíróníkà 27:10 BMY

10 Ẹ̀kéje fún oṣù kéje jẹ́ Hélésì ará Pélónì, ará Éfíráímù. Ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni o wà ní ìpín Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:10 ni o tọ