1 Kíróníkà 27:9 BMY

9 Ẹ̀kẹfà fún oṣù kẹfà jẹ́ Írà ọmọ Íkéṣì, ará Tékóì. Ọkùnrin ẹgbàá méjìlá (24,000) ni ó wà ní ìpín Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:9 ni o tọ