1 Kíróníkà 27:24 BMY

24 Jóábù ọmọ Ṣérúyà bẹ̀rẹ̀ sí ní kàwọ́n, ṣùgbọ́n kò parí kíkà wọ́n nítorí, ìbínú dé sórí àwọn Ísírẹ́lì nipaṣẹ̀ kíka iye àti iye náà, a kò kọọ́ sínu ìwé ìtàn ayé ti ọba Dáfídì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:24 ni o tọ