1 Kíróníkà 27:23 BMY

23 Dáfídì kò kọ iye àwọn ọkùnrin náà ní ogún ọdún sẹ́yìn tàbí dín nítori Olúwa ti ṣe ìlerí lati ṣe Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí iye ìràwọ̀ ojú ọ̀run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:23 ni o tọ