1 Kíróníkà 29:11 BMY

11 Tìrẹ Olúwa ni títóbi àti agbára pẹ̀lú ìyìnàti ọlá ńlá àti dídán,nítorí tí gbogbo nǹkan ní ọ̀run àti ayé jẹ́ tìrẹ.Tìrẹ Olúwa ni ìjọba;a gbé ọ ga gẹ́gẹ́ bí orí lórí ohun gbogbo.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:11 ni o tọ