1 Kíróníkà 29:10 BMY

10 Dáfídì yin Olúwa níwájú gbogbo àwọn tí ó péjọ, wí pé,“Ìyìn ni fún Ọ, Olúwa,Ọlọ́run baba a wa Ísírẹ́lì,láé àti láéláé.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:10 ni o tọ