1 Kíróníkà 29:9 BMY

9 Àwọn ènìyàn láyọ̀ nínú ìṣesí àtọkànwá fi sílẹ̀ àwọn olórí wọn, nítorí tí wọ́n ti fi sílẹ̀ ní ọ̀fẹ́ pẹ̀lú gbogbo ọkàn sí Olúwa. Dáfídì ọba pẹ̀lú yọ̀ gidigidi.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:9 ni o tọ