1 Kíróníkà 29:14 BMY

14 “Ṣùgbọ́n Ta ni èmi, àti ta ni àwọn ènìyàn mi, tí a fi lè fi sílẹ̀ tinútínú bí irú èyí? Gbogbo nǹkan wá láti ọ̀dọ̀ rẹ, àwa sì ti fífún ọ láti ara ohun tí ó wá láti ọwọ́ rẹ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:14 ni o tọ