1 Kíróníkà 29:15 BMY

15 Àwa jẹ́ àjèjì àti àlejò ní ojú rẹ gẹ́gẹ́ bí baba ńlá a wa, àwọn ọjọ́ wa lórí ilẹ̀ ayé rí bí òjìji láìsí ìrètí.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:15 ni o tọ