1 Kíróníkà 3:4 BMY

4 Ẹ̀kẹfà ni a bí fún Dáfídì ni Hébúrónì, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.Dáfídì sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́talélọ́gbọ̀n (33).

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3

Wo 1 Kíróníkà 3:4 ni o tọ