1 Kíróníkà 3:5 BMY

5 Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un:Ṣámúyà, Ṣóbábù, Náhátì àti Sólómónì. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bátíṣébà ọmọbìnrin Ámíélì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3

Wo 1 Kíróníkà 3:5 ni o tọ