1 Kíróníkà 4:2 BMY

2 Réáíà ọmọ Ṣóbálì ni baba Jáhátì, àti Jáhátì baba Áhúmáyì àti Láhádì. Àwọn wọ̀nyí ni ẹ̀yà ará Ṣórà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:2 ni o tọ