1 Kíróníkà 6:70 BMY

70 Pẹ̀lú láti apá ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fún Ádérì àti Bíléámù lápapọ̀ pẹ̀lú pápá oko tútù ilẹ̀ wọn, fún ìyókù àwọn ìdílé Kóhátítè.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6

Wo 1 Kíróníkà 6:70 ni o tọ