1 Kíróníkà 8:13 BMY

13 Pẹ̀lú Béríà àti Ṣémà, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Áíjálónì àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gátì kúrò.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8

Wo 1 Kíróníkà 8:13 ni o tọ