1 Ọba 1:11 BMY

11 Nígbà náà ni Nátanì bèrè lọ́wọ́ Bátíṣébà, ìyá Sólómọ́nì pé, “Ǹjẹ́ ìwọ kò gbọ́ pé Àdóníjà, ọmọ Hágítì ti jọba láìjẹ́ pé Dáfídì Olúwa wa mọ̀ síi?

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:11 ni o tọ