1 Ọba 1:38 BMY

38 Nígbà náà ni Sadókù àlùfáà, Nátanì wòlíì, Bénáyà ọmọ Jéhóiádà, àwọn ará Kérétì àti Pélétì sì sọ̀kalẹ̀ wá wọ́n sì gbé Sólómónì gun ìbaka Dáfídì ọba wá sí Gíhónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:38 ni o tọ