1 Ọba 11:15 BMY

15 Ó sì ṣe, nígbà tí Dáfídì wà ní Édómù, Jóábù olórí ogun sì gòkè lọ láti sìn àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì ti a pa lójú ogun, ó sì pa gbogbo ọkùnrin Édómù.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:15 ni o tọ