1 Ọba 11:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n Hádádì sá lọ sí Éjíbítì pẹ̀lú àwọn ará Édómù tí wọ́n jẹ́ ìránṣẹ́ bàbá rẹ̀. Hádádì sì wà ní ọmọdé nígbà náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:17 ni o tọ