1 Ọba 11:40 BMY

40 Sólómónì wá ọ̀nà láti pa Jéróbóámù, ṣùgbọ́n Jéróbóámù sá lọ sí Éjíbítì, sọ́dọ̀ Ṣísákì ọba Éjíbítì, ó sì wà níbẹ̀ títí Sólómónì fi kú.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:40 ni o tọ