1 Ọba 12:11 BMY

11 Baba mi ti gbé àjàgà wúwo lé e yín; Èmi yóò sì fi kún àjàgà yín. Baba mi ti fi pàsán nà yín; Èmi yóò fi àkéekèe nà yín.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:11 ni o tọ