1 Ọba 12:14 BMY

14 Ó sì tẹ̀lé ìmọ̀ràn àwọn ọmọdé, ó sì wí pé, “Baba mí sọ àjàgà yín di wúwo; Èmi yóò sì jẹ́ kí ó wúwo sí i; Baba mi fi pàsán nà yín; Èmi yóò fí àkéekèe nà yín.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:14 ni o tọ