1 Ọba 12:21 BMY

21 Nígbà tí Réhóbóámù sì dé sí Jérúsálẹ́mù, ó kó gbogbo ilé Júdà jọ, àti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì; ọ̀kẹ́ mẹ́sàn án (180,000) ènìyàn tí a yàn, tí wọ́n ń ṣe ológun, láti bá ilé Ísírẹ́lì jà àti láti mú ìjọba náà padà bọ̀ sọ́dọ̀ Réhóbóámù, ọmọ Sólómónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:21 ni o tọ