1 Ọba 12:25 BMY

25 Nígbà náà ni Jéróbóámù kọ́ Ṣékémù ní òkè Éfúráímù, ó sì ń gbé inú rẹ̀. Láti ibẹ̀ ó sì jáde lọ, ó sì kọ́ Pénúélì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:25 ni o tọ