1 Ọba 12:27 BMY

27 Bí àwọn ènìyàn wọ̀nyí bá gòkè lọ láti ṣe ìrúbọ ní ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù, wọn yóò tún fi ọkàn wọn fún Olúwa wọn, Réhóbóámù ọba Júdà. Wọn yóò sì pa mí, wọn yóò sì tún padà tọ Réhóbóámù ọba Júdà lọ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:27 ni o tọ