1 Ọba 12:31 BMY

31 Jéróbóámù sì kọ́ ojúbọ sórí ibi gíga, ó sì yan àwọn àlùfáà láti inú àwọn ènìyàn bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọn kì í ṣe inú àwọn ọmọ Léfì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:31 ni o tọ