1 Ọba 12:5 BMY

5 Réhóbóámù sì wí fún wọn pé, “Ẹ lọ ná títí di ọjọ́ mẹ́ta, nígbà náà ni kí ẹ padà tọ̀ mí wá.” Àwọn ènìyàn náà sì lọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 12

Wo 1 Ọba 12:5 ni o tọ