1 Ọba 13:12 BMY

12 Baba wọn sì béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “Ọ̀nà wo ni ó gbà?” Àwọn ọmọ rẹ̀ sì fi ọ̀nà tí ènìyàn Ọlọ́run láti Júdà gbà hàn án.

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:12 ni o tọ