1 Ọba 13:25 BMY

25 Àwọn ènìyàn tí ó ń kọjá sì rí òkú náà, wọ́n sì lọ, wọ́n sì sọ ọ́ ní ìlú tí wòlíì àgbà náà ń gbé.

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:25 ni o tọ