1 Ọba 13:29 BMY

29 Nígbà náà ni wòlíì náà gbé òkú ènìyàn Ọlọ́run náà, ó sì gbé e lé orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́, ó sì gbé e padà wá sí ìlú ara rẹ̀ láti ṣọ̀fọ̀ fún un àti láti sin ín.

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:29 ni o tọ