1 Ọba 13:3 BMY

3 Ní ọjọ́ kan náà ènìyàn Ọlọ́run sì fún wọn ní àmì kan wí pé: “Èyí ni àmì tí Olúwa ti kéde: kíyèsii, pẹpẹ náà yóò ya, eérú tí ń bẹ lórí rẹ̀ yóò sì dànù.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:3 ni o tọ