1 Ọba 13:32 BMY

32 Nítorí iṣẹ́ tí ó jẹ́ nípa ọ̀rọ̀ Olúwa sí pẹpẹ tí ó wà ní Bétélì àti sí gbogbo ojúbọ lórí ibi gíga tí ń bẹ ní àwọn ìlú Samáríà yóò wá sí ìmúṣẹ dájúdájú.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:32 ni o tọ