1 Ọba 13:5 BMY

5 Lẹ́sẹ̀ kan náà, pẹpẹ ya, eérú náà sì dànù kúrò lórí pẹpẹ náà gẹ́gẹ́ bí àmì tí ènìyàn Ọlọ́run ti fi fún un nípa ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:5 ni o tọ