1 Ọba 13:7 BMY

7 Ọba sì wí fún ènìyàn Ọlọ́run náà pé, “Wá bá mi lọ ilé, kí o sì wá nǹkan jẹ, èmi yóò sì fi ẹ̀bùn fún ọ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:7 ni o tọ