1 Ọba 14:18 BMY

18 Wọ́n sì sin ín, gbogbo Ísírẹ́lì sì ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti wí láti ẹnu ìránṣẹ́ rẹ̀, Ábíjà wòlíì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 14

Wo 1 Ọba 14:18 ni o tọ