1 Ọba 14:28 BMY

28 Nígbàkígbà tí ọba bá sì lọ sí ilé Olúwa Wọ́n á rù wọ́n, wọ́n á sì mú wọn padà sínú yàrá olùṣọ́.

Ka pipe ipin 1 Ọba 14

Wo 1 Ọba 14:28 ni o tọ