1 Ọba 15:17 BMY

17 Bááṣà, ọba Ísírẹ́lì sì gòkè lọ sí Júdà, ó sì kọ́ Rámà láti má jẹ́ kí ẹnikẹ́ni jáde tàbí wọlé tọ Áṣà ọba lọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:17 ni o tọ