1 Ọba 15:2 BMY

2 ó sì jọba ní ọdún mẹ́ta ní Jérúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Máákà, ọmọbìnrin Ábúsálómù.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:2 ni o tọ