1 Ọba 15:22 BMY

22 Nígbà náà ni Áṣà ọba kéde ká gbogbo Júdà, kò dá ẹnìkan sí: wọ́n sì kó òkúta àti igi tí Bááṣà ń lò kúrò ní Rámà. Áṣà ọba sì fi wọ́n kọ́ Gébà ti Bẹ́ńjámínì àti Mísípà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:22 ni o tọ