1 Ọba 15:24 BMY

24 Áṣà sì sùn pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀ ní ìlú Dáfídì bàbá rẹ̀. Jèhóṣáfátì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:24 ni o tọ