1 Ọba 15:26 BMY

26 Ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, ó sì rìn ní ọ̀nà bàbá rẹ̀ àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó mú Ísírẹ́lì dá.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:26 ni o tọ