1 Ọba 15:34 BMY

34 Ó sì ṣe búburú níwájú Olúwa, ó sì rìn ní ọ̀nà Jéróbóámù àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó ti mú Ísírẹ́lì ṣẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:34 ni o tọ