1 Ọba 16:15 BMY

15 Ní ọdún kẹtàdínlọ́gbọ̀n Áṣà ọba Júdà, ni Ṣímírì jọba ọjọ́ méje ní Tírísà. Àwọn ọmọ ogun sì dó ti Gíbétónì, ìlú àwọn ará Fílístínì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 16

Wo 1 Ọba 16:15 ni o tọ