1 Ọba 17:17 BMY

17 Ó sì ṣe lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ọmọ obìnrin tí ó ni ilé náà ṣe àìsàn, àìsàn náà sì le tó bẹ́ẹ̀, tí ó fi kú.

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:17 ni o tọ