1 Ọba 18:43 BMY

43 Ó sì wí fún ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé, “Lọ, kí o sì wo ìhà òkun, òun sì gòkè lọ, ó sì wò.”Ó sì wí pé, “Kò sí nǹkan níbẹ̀.”Ó sì wí pé, “Tún lọ nígbà méje.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:43 ni o tọ