1 Ọba 19:16 BMY

16 Tún fi òróró yan Jéhù ọmọ Nímísì ní ọba lórí Ísírẹ́lì, àti kí o fi òróró yan Èlíṣà ọmọ Sáfátì, ará Ábélí-Méhólà ní wòlíì ní ipò rẹ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:16 ni o tọ