1 Ọba 2:8 BMY

8 “Àti kí o rántí, Ṣíméhì ọmọ Gérà ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì tí Báhúrímù wà pẹ̀lú rẹ̀, tí ó bú mi ní èébú tí ó korò ní ọjọ́ tí mo lọ sí Máhánáímù. Nígbà tí ó sọ̀kalẹ̀ wá pàdé mi ní Jọ́dánì, mo fi Olúwa búra fún un pé: ‘Èmi kì yóò fi idà pa ọ́.’

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:8 ni o tọ