1 Ọba 22:19 BMY

19 Míkáyà sì tún wí pé, “Nítorí náà gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa: Mo rí Olúwa jókòó lórí ìtẹ́ rẹ̀ pẹ̀lú gbogbo ogun ọ̀run dúró ní apá ọ̀tún àti ní apá òsì rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:19 ni o tọ