1 Ọba 22:53 BMY

53 Ó sì sin Báálì, ó sì ń bọ Báálì, ó sì mú Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì bínú, gẹ́gẹ́ bí i baba rẹ̀ ti ṣe.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:53 ni o tọ