1 Ọba 4:19 BMY

19 Gébérì ọmọ Úrì ní Gílíádì; orílẹ̀ èdè Ṣíhónì ọba àwọn ará Ámórì àti orílẹ̀ èdè Ógù ọba Básánì. Òun nìkan ni ìjòyè lórí ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin 1 Ọba 4

Wo 1 Ọba 4:19 ni o tọ